Lúùkù 14:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì rán ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ ní wákàtí àsè alẹ́ náà láti sọ fún àwọn tí a ti pè pé, ‘Ẹ wá; nítorí ohun gbogbo ṣe tán!’

Lúùkù 14

Lúùkù 14:16-19