Lúùkù 13:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ó sì ti ilẹ̀ ìlà òòrùn, àti ìwọ̀-òòrùn wá, àti láti àríwá, àti gúsù wá, wọn ó sì jókòó ní ìjọba Ọlọ́run.

Lúùkù 13

Lúùkù 13:23-35