Lúùkù 13:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Níbẹ̀ ni ẹkún àti ìpahínkeke yóò wà, nígbà tí ẹ̀yin ó rí Ábúráhámù, àti Ísáákì, àti Jákọ́bù, àti gbogbo àwọn wòlíì, ní ìjọba Ọlọ́run, tí a ó sì ti ẹ̀yin sóde.

Lúùkù 13

Lúùkù 13:21-32