Lúùkù 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmí sì wí fún yín, Ẹ bèèrè, a ó sì fifún un yín; ẹ wá kiri, ẹ̀yin ó sì rí; ẹ kànkùn, a ó sì ṣí i sílẹ̀ fún yín.

Lúùkù 11

Lúùkù 11:5-13