Lúùkù 11:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wí fún yín, bí òun kò tilẹ̀ ti fẹ́ dìde kí ó fifún un nítorí tí í ṣe ọ̀rẹ́ rẹ̀, ṣùgbọ́n nítorí àwíìyánu rẹ̀, yóò dìde, yóò sì fún un pọ̀ tó bí ó ti ń fẹ́.

Lúùkù 11

Lúùkù 11:5-11