Lúùkù 11:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègbé ni fún yín, ẹ̀yin amòfin, nítorí tí ẹ̀yin ti mú kọ́kọ́rọ́ ìmọ̀ kúrò; ẹ̀yin tìkára yín kò wọlé, àwọn tí sì ń wọlé, ni ẹ̀yin ń dí lọ́wọ́.”

Lúùkù 11

Lúùkù 11:42-54