Lúùkù 11:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ẹ̀jẹ̀ Ábélì wá, títí ó sì fi dé ẹ̀jẹ̀ Sakaráyà, tí ó ṣègbé láàrin pẹpẹ àti tẹ́ḿpìlì: lóòótọ́ ni mo wí fún yín.

Lúùkù 11

Lúùkù 11:41-52