Lúùkù 11:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ba ṣe pé nípa Béélísébúbù ni èmi fi ń lé àwọn ẹ̀mí ẹ̀ṣù jáde, nípa tani àwọn ọmọ yín fi ń lé wọn jáde, nítorí náà àwọn ni yóò ṣe onídájọ́ yín.

Lúùkù 11

Lúùkù 11:18-26