Lúùkù 11:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Sàtánì sì yapa sí ara rẹ̀, ìjọba rẹ̀ yóò ha ṣe dúró? Nítorí ẹ̀yin wí pé, nípa Béélísébúbù ni èmi fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.

Lúùkù 11

Lúùkù 11:10-22