Lúùkù 1:75 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní mímọ́ ìwà àti ní òdodo níwájú rẹ̀, ní ọjọ́ ayé wa gbogbo.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:70-76