Lúùkù 1:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ó pọ̀, Ọmọ Ọ̀gá-ògo jùlọ ni a ó sì máa pè é: Olúwa Ọlọ́run yóò sì fi ìtẹ́ Dáfídì baba rẹ̀ fún:

Lúùkù 1

Lúùkù 1:26-37