Lúùkù 1:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ óò lóyún nínú rẹ, ìwọ ó sì bí ọmọkùnrin kan, ìwọ ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní JÉSÙ.

Lúùkù 1

Lúùkù 1:27-32