Léfítíkù 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó pa akọ màlúù àti àgbò bí ẹbọ àlàáfíà fún àwọn ènìyàn. Àwọn ọmọ rẹ̀ gbé ẹ̀jẹ̀ ẹran náà fún un, ó sì wọn yí pẹpẹ náà ká.

Léfítíkù 9

Léfítíkù 9:16-24