Léfítíkù 9:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tún mu ẹbọ ohun jíjẹ wá, ó bu ẹ̀kúnwọ́ kan nínú rẹ̀, ó sì sun ún lórí pẹpẹ ní àfikún ẹbọ sísun tí àárọ̀.

Léfítíkù 9

Léfítíkù 9:9-21