Léfítíkù 26:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ebi náà yóò pa yín débi pé ẹ ó máa jẹ ẹran ara àwọn ọmọ yín ọkùnrin, àti àwọn ọmọ yín obìnrin.

Léfítíkù 26

Léfítíkù 26:28-33