Léfítíkù 26:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìbínú mi èmi yóò korò sí yín, èmi tìkara mi yóò fìyà jẹ yín ní ìgbà méje nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín.

Léfítíkù 26

Léfítíkù 26:27-38