Léfítíkù 23:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe ṣe iṣẹ́ kankan ní ọjọ́ náà, torí pé ọjọ́ ètùtù ni, nínú èyí tí a ń ṣe ètùtù fún yín níwájú Olúwa Ọlọ́run yín.

Léfítíkù 23

Léfítíkù 23:22-32