Léfítíkù 23:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọjọ́ kẹwàá oṣù keje yìí ni ọjọ́ ètùtù. Ẹ ni ìpàdé àjọ mímọ́, kí ẹ sì ṣẹ́ ara yín kí ẹ sì mú ọrẹ tí a fi iná ṣe wá fún Olúwa.

Léfítíkù 23

Léfítíkù 23:23-35