Léfítíkù 22:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Kí àwọn àlùfáà pa ìlànà mi mọ́, kí wọn má baà jẹ̀bi, kí wọn sì kú nítorí pé wọ́n ṣe ọrẹ wọ̀nyí pẹ̀lú fífojútẹ́ḿbẹ́lú wọn. Èmi ni Olúwa tí ó sọ wọ́n di mímọ́.

Léfítíkù 22

Léfítíkù 22:1-15