Léfítíkù 22:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Kò sí ẹnikẹ́ni lẹ́yìn ìdílé àlùfáà tí ó le jẹ ọrẹ mímọ́ náà, bẹ́ẹ̀ ni, àlejò àlùfáà tàbí alágbàṣe rẹ̀ kò le jẹ ẹ́.

Léfítíkù 22

Léfítíkù 22:1-18