Léfítíkù 19:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ jalè.“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ parọ́.“ ‘Ẹ kò gbọdọ̀ tan ara yín jẹ.

Léfítíkù 19

Léfítíkù 19:4-12