Léfítíkù 16:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọjọ́ yìí yóò jẹ́ ọjọ́ ìsinmi pátapáta fún un yín: ẹ̀yin yóò sì ṣẹ́ ara yín: Èyí yóò sì jẹ́ ìlànà títí láé.

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:22-34