Léfítíkù 16:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Torí pé ní ọjọ́ yìí ni àlùfáà yóò ṣe ètùtù fún yín láti sọ yín di mímọ́: kí ẹ̀yin baà le mọ́ níwájú Olúwa yín kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ yín gbogbo.

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:21-34