Léfítíkù 15:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọkùnrin kan bá bá obìnrin lòpọ̀ tí nǹkan ọkùnrin sì tú jáde lára rẹ̀. Àwọn méjèèjì gbọdọ̀ fi omi wẹ̀: kí wọ́n sì wà ní ipò àìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Léfítíkù 15

Léfítíkù 15:16-25