Léfítíkù 15:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yálà àwọ̀ tàbí aṣọ tí nǹkan ọkùnrin bá dà sí lórí ni kí ẹ fọ̀: yóò sì wà ní ipò àìmọ́ di ìròlẹ́.

Léfítíkù 15

Léfítíkù 15:9-20