Léfítíkù 14:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí ó mú wọn wá ní ọjọ́ kẹjọ fún ìwẹ̀nùmọ́ rẹ̀ ṣíwájú àlùfáà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé níwájú Olúwa.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:13-32