Léfítíkù 14:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti àdàbà méjì tàbí ẹyẹlé méjì èyí tí agbára rẹ̀ ká ọ̀kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti èkejì fún ẹbọ sísun.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:12-29