Léfítíkù 13:59 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìlànà wọ̀nyí wà fún àwọn ohun tí ẹ̀tẹ̀ bàjẹ́ níbi, aṣọ irun àgùtàn aṣọ funfun, aṣọ títa, aṣọ híhun tàbí ohun èlò awọ, láti fi hàn bóyá wọ́n wà ní mímọ́ tàbí àìmọ́.

Léfítíkù 13

Léfítíkù 13:54-59