Léfítíkù 13:58 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aṣọ náà, aṣọ títa náà, aṣọ híhun náà tàbí ohun èlò àwọ náà tí a ti fọ̀ tí ó sì mọ́ lọ́wọ́ ẹ̀tẹ̀ náà ni kí a tún fọ̀ lẹ́ẹ̀kan sí i. Yóò sì di mímọ́.”

Léfítíkù 13

Léfítíkù 13:51-59