Léfítíkù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó pa ọ̀dọ́ akọ màlúù náà níwájù Olúwa, lẹ́yìn náà ni àwọn àlùfáà tí í se ọmọ Árónì yóò gbé ẹ̀jẹ̀ ẹran náà, wọn yóò sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ náà yí pẹpẹ tí ó wà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ àjọ ká.

Léfítíkù 1

Léfítíkù 1:1-11