Léfítíkù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé orí ẹbọ sísun náà yóò sì jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà dípò o rẹ̀, yóò sì jẹ́ ètùtù fún un.

Léfítíkù 1

Léfítíkù 1:1-6