Léfítíkù 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó fi omi san nǹkan inú àti àwọn ẹsẹ̀ rẹ̀, kí àlùfáà sì gbé gbogbo rẹ̀ wá láti sun lórí pẹpẹ. Ó jẹ́ ọrẹ ẹbọ sísun tí a fi iná se, àní òórùn dídùn sí Olúwa

Léfítíkù 1

Léfítíkù 1:10-15