Kólósè 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

íwọ̀n ìgbà tí a ti jí yín dìde pẹ̀lú Kírísítì ẹ máa ṣafẹrí àwọn nǹkan tí ń bẹ lókè, níbi tí Kírísítì gbé wà tí ó jòkòó ní ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run.

Kólósè 3

Kólósè 3:1-6