Kólósè 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn nǹkan tí ó ní àfarawé ọgbọ́n nítòótọ́, ni àdábọwọ́ ìsìn, àti ìrẹ̀lẹ̀, àti ìpọn-ara-lójú, ṣùgbọ́n tí kò ni èrè hàn nínú fún ìfẹ́kúfẹ ara.

Kólósè 2

Kólósè 2:22-23