Kólósè 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ẹni tí a kò fí ìkọlà tí a fi ọwọ́ kọ kọ yín ní Ilà, ni bíbọ ara ẹ̀ṣẹ̀ sílẹ̀, nínú ìkọlà Kírísítì.

Kólósè 2

Kólósè 2:4-17