Kólósè 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ẹ̀yin sì ní ohun gbogbo ní kíkún nínú Kírísítì, ẹni tí i ṣe orí fún gbogbo agbára àti àṣẹ.

Kólósè 2

Kólósè 2:7-17