Kólósè 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbàkúùgbà tí a bá ń gbàdúrà fún un yín ni a máa ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run Baba Olúwa wa Jésù Kírísítì.

Kólósè 1

Kólósè 1:1-7