Kólósè 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sí àwọn ẹni mímọ́ àti àwọn arákùnrin nínú Kírísítì tí wọ́n ń gbé ní ìlú Kólósè.Oore-ọ̀fẹ́ àti àlàáfíà fún-un yín láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa.

Kólósè 1

Kólósè 1:1-11