Jóṣúà 5:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olórí ogun Olúwa sì dá a lóhùn pé, “Bọ́ sálúbàtà rẹ kúrò ní ẹṣẹ̀ rẹ, nítorí pé ibi tí ìwọ dúró sí yìí, ilẹ̀ mímọ́ ni.” Jóṣúà sì ṣe bẹ́ẹ̀.

Jóṣúà 5

Jóṣúà 5:9-15