Jóṣúà 19:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà náà gba ìhà ìwọ̀-oòrùn lọ sí Ásínótì, Tabori ó sì jáde ní Húkókì. Ó sì dé Sébúlúnìe ní ìhà gúsù, Ásíẹ́rì ní ìhà ìwọ̀-oòrùn àti Jọ́dánì ní ìhà ìlà-oòrùn.

Jóṣúà 19

Jóṣúà 19:28-36