Jóṣúà 19:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà wọn lọ láti Hẹ́lẹ́fì àti igi ńlá ní Sááná nímù; kọjá lọ sí Ádámì Nékébù àti Jábínẹ́ẹ́lì dé Lákúmì, ó sì pín ní Jọ́dánì.

Jóṣúà 19

Jóṣúà 19:25-41