Jóṣúà 17:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣúà dá wọn lóhùn pé, “Bí ẹ bá pọ̀ bẹ́ẹ̀, tí òkè ìlú Éfúráímù bá kéré fún yin, ẹ gòkè lọ sí igbó kí ẹ sì sán ilẹ̀ òkè fún ara yín ní ibẹ̀ ní ilẹ̀ àwọn ará Pérísì àti ará Réfì.”

Jóṣúà 17

Jóṣúà 17:13-18