Jóṣúà 17:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹ̀yà Jósẹ́fù méjèèje sì sọ fún Jóṣúà pé, “Kí ló dé ìwọ fi fún wa ní ìpín ilẹ̀ kan àti ìdá kan ní ìní? Nítorí àwa jẹ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn tí Olúwa ti bùkún lọ́pọ̀lọpọ̀.”

Jóṣúà 17

Jóṣúà 17:7-18