Jóṣúà 15:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ààlà wọn ní ìhà ìlà-oòrùn ní Òkun Iyọ̀ títí dé ẹnu Jọ́dánì.Ààlà àríwá bẹ̀rẹ̀ láti etí òkun ní ẹnu Jọ́dánì,

Jóṣúà 15

Jóṣúà 15:1-14