Jóṣúà 15:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tún kọjá lọ sí Ásímónì, ó sì papọ̀ mọ́ Wádì ti Éjíbítì, ó parí sí òkun. Èyí ni ààlà wọn ní ìhà gúsù.

Jóṣúà 15

Jóṣúà 15:1-11