Jóṣúà 15:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ótíniẹ́lì ọmọ Kénásì, arákùnrin Kélẹ́bù, sì gbà á, báyìí ni Kélẹ́bù sì fi ọmọbìnrin rẹ̀ Ákísà fún un ní ìyàwó.

Jóṣúà 15

Jóṣúà 15:11-20