Jóṣúà 15:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kélẹ́bù sì wí pé, “Èmi yóò fi ọmọbìnrin mi Ákísà fún ọkùnrin tí ó bá kọlu Kiriati Séférì, tí ó sì gbà á ní ìgbeyàwó.”

Jóṣúà 15

Jóṣúà 15:12-22