Jóòbù 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí mo wí pé, ibùsùn mi yóò tù mí lára,ìtẹ́ mi yóò gbé ẹrù ìráhùn mi pẹ̀lú.

Jóòbù 7

Jóòbù 7:11-16