Jóòbù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ rẹ̀ kò jìnnà sí ewu,a sì tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀ lójú ibodè,bẹ́ẹ̀ ni kò sí aláàbò kan.

Jóòbù 5

Jóòbù 5:2-12