Jóòbù 37:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Góòlù dídán ti inú ìhà àríwá jádewá; lọ́dọ̀ Ọlọ́run ni ọláńlá ẹ̀rùn ńlá.

Jóòbù 37

Jóòbù 37:20-24